Onimo aye
Come for your spiritual problems GOD is power
- OGUN ALAGAN TABI AIROMOBI. ( ki obinrin leloyun ati bimo ni irorun)Agbebo adie kan, koko efun mesan, koko osun mesan, ewe jokoje ti ko dalu mesan, ewe ailu ti ko dalu mesan, odd atare meta. Ao pa adiye adiye naa, ao ki gbogbo awon eronja yii si nu re lati idi ti yio gba tan. Ao wajo, ao lokuna, ao sese wa rosinu ado kan to le gba. Ti obinrin na ba ti pari nkan osu re, ohun ati oko re won yio fi fokomu lale ojo naa won yoo si barawon sun. Ti won bati mu eko naa tan, won koni de ado yen ti won yio fi ba ara won sun, ti oko na bati da ato si (release) oko na koni yo oko (p***s) re kuro, yio wa de ado yen pada ki o to yo oko (p***s) re kuro. Won yio gbe ado yii si igberi bi ti won bafesun tabi ba ara won sun ni o. Tested ok.
14/10/2022
Come for Ur sepritual problem
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the public figure
Telephone
Website
Address
Ifon