Eko News.Com

Eko News.Com

Share

It Is An Independent Media Platform, Crashing Information Barrier, Rooted In Lagos State, Nigeria.

26/03/2026

DIGBI LA WÀ LẸ́YÌN ÀÀRẸ TINUBU FUN SAA KEJÌ | ỌMỌ BÍBÍ ÌPÍNLẸ̀ ÈKÓ NI GÓMÌNÀ TÓ Ń BỌ̀ TI GBỌ́DỌ̀ JÁDE

|Ogidiolu|

Egbé àwọn laamilaaka ọmọ bibi Ìpínlẹ̀ Èkó fẹnu kò láti satileyin fún Ààrẹ Ahmed Bọlá Tinubu GCFR níbi ètò idibo ọdún 2026 láti lọ fún ṣáá kejì níbi ìpàdé Egbe náà tó wáyé lọ́jọ́ kejìdínlógún oṣù kẹta ọdún 2026.

Lára àwọn ọ̀rọ̀ tó tún jeyo níbi ìpàdé náà ni pé ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Èkó ló gbọ́dọ̀ jẹ Gomina, igbá-kejì Gomina àti agbenuso ilé ìgbìmò asofin lódun 2027.

Wọn ṣàlàyé sínú atejade tí alákòóso ìpàdé náà ìyẹn Chief Dr Adesunbo Onitiru buwolu pé àfojúsùn àwọn ipò yìí ni láti mú ibadogogba, didaabo bo idanimo wá àti láti tunbo jẹ́ káwọn alẹ́nulóró túnbọ̀ farajin sí ètò isejoba Ìpínlẹ̀ Èkó.

Àwọn amuye tí ẹgbẹ́ náà là kalẹ pé ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ díje dupo gbọ́dọ̀ ní ni:
* Ó gbodo jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlè Èkó
* ó gbodo ní àwọn ìwé ẹ̀rí tí ó tó
* ó gbọ́dọ̀ ní òye nípa ètò adarí yálà leka ìjọba tàbí tí aladani
* ó gbọ́dọ̀ ní àwọn ẹ̀rí pé olóòótọ́ ènìyàn ní, tí kò sí ní àkọsílẹ̀ ìwà ọ̀daràn kankan rí
* ó gbọdọ ní àwọn iṣẹ́ àkànṣe tó ti ṣe láṣẹ yọrí nipinle Èkó tàbí làwọn Ìpínlẹ̀ tó yìí ká.
* ó gbó mú ebi àti àwọn ènìyàn rẹ lókun kúndùn
* ó gbodo mo bí wọn ṣe ń ṣíṣe pò pẹ̀lú àwọn ènìyàn, ó sì gbọdọ lè dá dúró tí kò bá sí labasisepo.

Egbe àwọn ọmọ bíbí ìpínlè Èkó tún tesiwaju pé àwọn yóò kópa nínú gbogbo igbese àti yàn ẹni tó kún ojú òṣùwọ̀n láti wà láwọn ipò yìí fún ọjọ́ iwájú Ìpínlẹ̀

14/11/2025

WO GOLI SEGBE, JU BOOLU SAWON!
Kile ri so si aworan Oshimen yii?
Nig 4-1 Gabon

Want your business to be the top-listed Media Company in Lagos?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Telephone

Website

Address

Ikeja
Lagos