ASIRI AWON AGBA
We created this group to assist people in all ways of life like.... Any kind of sickness, marital
*OSE ATUDE ASINA TIPATIPA TOTUN SISE CASHOUT*
🅰o lo wa opolo ijokun ooye kan, egbo tude, epo obo, ata ijosi 16, ao gun won papo, ao fi ose ko, ao fi Bintu de dada, ao gbe opolo ooye miran si isale ike funfun, ao wa ko ose yi bo mole, ao fi ikode kan gun ose yi lori, ao gbe pamo fun ojo meta, ao bere wiwe re leyin ojo keta. Bi omo yahoo bawe ose yi yio gba owo gidi.
11/07/2025
*OSE ATUDE AJAIDE TO GBONA/ OTUN DARA FUN OMO YAHOO*
🅰o lo wa egbo tude tutu, ewe tude tutu, epo obo, egbo egbesi tutu, egbo ipeta tutu, ewe sawerepepe tutu, ao gun won kio kuna dada, ao wa fi ose Ghana popo dada, omi agbon lama fipo po dada, ao ko sinu ike funfun, leyin ojo keta ao ma buwe lararo tabi alale.
*OGUN TI AFI NYANJU EJO TOBA LAGBARA/ TABI TI AFI NTU EJO KA*
🅰o lo wa eku eliri, iru pete ti ko niyo, owu dudu ati owu funfun. Ao wa ninu ile ni ihoho omoluabi, ao san iru yen mo ara eku yi dada ti ara re koni han mo rara, ao wa gbe dani, ao wa so wipe..... Igbodi miramiramira*3, okunkun birimubirimubirimu*3, oro ...ati... bayibayi tani yio bi erin yii bi efon, nigbati ile yio fimo eliri lasan lobi, ko soro nibe mo, oro.... ati... ti won nfa laarin ara won, ti won gberawon losi court lola ko soro nibe, ki won da ejo na nu ni.
Ao wa mo we ni owu imule, t**i ao fi wetan lao mape ohun yen si. Ao walo si aarin igbo, ao da ile ikan kekeke yen legbe, ao wa kibo, kia to ju sinu re, ao tun pe ohun yen si. Ao ma lole, awon ikan yen yio ti mole bo mole.
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Telephone
Website
Address
Iyana Ipaja
Lagos