Asejere Group
Asejere is a business magazine published from Lagos, Nigeria.
05/05/2024
Awọn ṣọọṣi, mọṣalaaṣi, ati otẹẹli ti wọn ti pa nitori ariwo laarin oṣu mẹta ree - Àṣejèrè Awon soosi, mosalaasi, ati ile igbafe tiye won to Orinlelooodunrun-o-din-meta (367) lawon ti gbe kokoro tipa laarin osu meta yii nipinle Eko. Komisanna to n ri si eto ayika ati oro omi nipinle naa, Ogbeni Tokunbo Wahab lo se bayii soro nibi ipade awon oniroyin to waye lojo Fraide to koja yii. Wahab....
05/05/2024
https://www.asejere.net/aworan-ayeye-ikeyin-egbin-orun-olorin-emi-bere-lonii/
AWORAN: Ayẹyẹ ikẹyin Egbin Ọrun, olorin ẹmi bẹrẹ lonii - Àṣejèrè Ayeye ikeyin ti won seto re fun Morenikeji Adeleke ti gbogbo eeyan mo si Egbin Orun maa bere lonii. Ojo kejidinlogun, osu kerin, odun yii ni omobinrin naa jade laye, gege bi Esther Igbekele, to je olorin emi bii tie naa ti so fun won ololufe re. Esther tun so pe oni, ojo Sannde ni […]
05/05/2024
Laarin oṣu mẹrin, awọn lanlọọdu Eko san ọọdunrun miliọnu naira owo-ori dukia funjọba - Àṣejèrè Owo tiye re je Oodunrun milionu naira nijoba ipinle Eko ti pa lori owo ori ile taa mo si Land Use Charges laarin osu merin odun yii. Ogbeni Ope George to je komisanna fun eto isuna owo nipinle naa lo se bayii soro fun awon oniroyin lose to koja ni Alausa, Ikeja ni Eko. George […]
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Lagos
23401